TRANSITIVE VERBS Flashcards
Bú - Má bù mi
Abuse - Don’t abuse me.
Gbà - Mo gba iṣẹ́ ìjọbá
Accept - I accepted the government work
Sìn - Bàbá sìn mi
Accompany - Father accompanied me.
Fẹ̀kùn kan - Wọ́n fẹ̀sùn kàn mi
Accuse - They accused me
Ro - Ara ń ro mí
Dùn - Ẹ̀yín ń dùn mí
Ache - The body aches me
Ache - The back aches me
Ṣe - Adé ṣe Ọba nínú erẹ́
Act - Ade acted as the king in the movie
Dáhùn - Wọn ò fẹ́ dáhùn ìbéèrè mi
Answer - They don’t want to answer my question
Takò - Àwọn ọ̀rẹ́ ẹ takò ó
Antagonise - His friends antagonized her.
Bẹ̀ - A ti bẹ̀ wọ́n
Apologize - We have apologized to them.
Súnmọ́ - A tí ń súnmọ́ yín
Approach - We are approaching you.
Fọwọ́ sí - Ìjọba ti fọwọ́ sí i
Approve - The government has approved it.
Ṣètò - Màmá ṣètò oúnjẹ fún wọ́n
Arrange - Mother arranged the food for them.
Mú - Ọlọ́pàá mú olè
Arrest - The policeman arrested the thief.
Bèèrè - Wọ́n bèèrè ìbéèrè
Bi - Wọ́n ti bi wọ́n
Ask - She has asked them.
Ask - They asked questions
Dojú ìjà kọ - Wọ́n dojú ìjà kọ ara wọn
Attack - They attacked each other.
Gbìnyànjú - Ṣé o lè gbìyànjú ẹ̀
Attempt - Can you attempt it.
Lọ - A gbọ́dọ̀ lọ sí ìpàdé
Wá - Wọ́n ma wá sí ìpàdé
Attend - We must attend the meeting.
Attend - They will attend the meeting
Yẹra fún - Ẹ yẹra fún wàhálà
Yàgò fún - Ẹ yàgò fún mi
Avoid - Avoid the problem.
Avoid - Avoid me.
Fòfin dè - Ìjọba ti fòfin de ọtí mímu
Ban - The government has banned the drinking of alcohol.
Wẹ̀ - Mò ń wẹ̀ ọmọ
Bathe - I am bathing the child.
Faradà - Ẹ ní láti faradà á
Bear - You have to endure it
Nà - Bàbá na ọmọ
Lù - Wọ́n ń lu ìlù
The father beat the child.
Beat - They are beating the drum.
Yẹ - Ìyà ò yẹ wọ́n
Befit - Suffering does not befit them.
Bẹ̀ - A bẹ̀ wọ́n
Beg - We begged her.