INTRASITIVE VERBS Flashcards
Gbà - Wọ́n gbà láti tẹ̀lẹ́ wa
Agree - They agreed to follow us.
Sọ̀ kalẹ̀ - A sọ̀ kalẹ̀ ní Ìbàdàn
Alight - We alighted at Ibadan.
Bínú - Mi ò bínú
Angry - I am not angry
Dáhùn - A ò lè dáhùn ìbéèrè
Fèsì - Wọn ò fèsì rárá
Answer
He didn’t answer at all.(Fèsì)
We can’t answer your questions. (Dáhùn)
Bẹ̀bẹ̀ - A ní láti bẹ̀bẹ̀
Apologize - We had to apologize.
Dé - Jọlá dé ní àná
Arrive - Jola arrived yesterday.
Bèèrè - Ẹ lè bèèrè
Ask - You can ask.
Lọ - Ṣe ẹ lọ sí ìpàdẹ́
Wá - Ṣé e má wá sí ilé mi
Attend
Did you go to the meeting?
Will you come to my house?
Bẹ̀rẹ̀ - A ma bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀la
Begin - We will begin tomorrow.
Wẹ̀ - Mi ò fẹ́ wẹ̀
Bathe - I don’t want to bathe.
Hùwà - Kílódé tí o hùwà báyẹn
Behave - Why did you behave like that
Gbàgbọ́ - Mo gbàgbọ́ pé ó ma wá
Believe - I believe that he will come.
Dalẹ̀ - Ẹnikẹni nínú yín ò gbọdọ̀ dalẹ̀
Betray - No one among you must betray.
Ṣẹ̀jẹ̀ - Ẹsẹ̀ ẹ ń ṣẹ̀jẹ̀
Bleed - His leg is bleeding.
Hó - Omi ti hó
Boil - The water is boiled.
Mí - Mí sí inú, mí sí ìta
Breathe - Breathe in, breathe out.
Jó - Iná ń jó
Burn - The fire is burning.
Bẹ́ - Ọ̀pá omi ti bẹ́
Burst - The water pipe has burst
Yí padà - Wọn ò lè yí padà
Change - They cannot change
Mọ́ - Aṣọ mi mọ
Clean - My clothes are clean
Wó - Ilé wọn wo ní àná
Collapse - His house collapsed yesterday.
Wà - Mo máa wá
Come - I will come
Wọ́pọ̀ - Ẹ̀nìyàn bí ìyá mi ò wọ́pọ̀
Common - Someone like my mother is not common.
Fìga gbága - Wọ́n á fìga gbága ní ọ̀la
Compete - They will compete tomorrow