ALL VERBS Flashcards
Pa - Wọn pa Ṣọlá ní òru àná
Murder - They murdered Sola at midnight.
Rún - Àwọn ọmọ rún ipanu wọn sí wẹ́wẹ́
Munch - The children munched their snack in pieces.
Sọ mọ - Kúnlé so mọ́ aya rẹ̀ níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó lánàá
Dì mọ́ - Ola dì mó ìyá rè láààrọ̀ yìí
Hug - Kunle hugged his wife at the wedding event yesterday
Ola huged his mother this morning
Tàsé - Níyì àti Adé tàsé ara wọn ní ilé-ìwòsàn ní àná
Miss - Níyì and Ade Missed each other at the hospital
Dárúkọ - Dárúkọ ìlú mẹ́ta ti o mọ̀
Mention - Mention three states you know.
Sin - Wọ́n máa sin òkú ìyá àgbà ní ọjọ́ sátidé tí ó ń bọ̀
Bury - They will bury grandma next Saturday.
Rù - Bimpe ru garawa omi sórí
Carry (on the head) - Bimpe carry a pale of water on the head
Lóyún - Ṣọlá ti lóyún
Pregnant - Sola is pregnant
Farabalẹ̀ - Ẹ ní láti farabalẹ̀
Calm down - You need to calm down
Lépa - Àwọn ọlọ́pàá lépa àwọn adigunjalè
Chase - Police chase after the robbers
Ṣe ìkẹ́ - Ọkọ ìyàwó ṣe ìkẹ́ aya rè
Cherish - The Groom cherished his wife
Gbè - Mo gbe omi òjò
Collect (rainwater) - I collected rainwater
Somọ́ - Ó sọmọ́ mi
Clung - She clung to me
Kọlu - Wọ́n kọlù ara wọn
Collide - The collided with each other.
Fọkan sí - Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń fọkàn sí àlàyé olùkọ́
Concentrate - - The students concentrate on the teacher’s explanations
Ṣépè fún - Má ṣépè fún mi
Géègún - Òbí ò gbọdọ̀ géègún fún àwọn ọmọ wọn
Curse - Do not curse me.
Parents must not curse their children
Ṣẹ́gun - A ma ṣégun ọ̀ta wa
Defeat
We will defeat our enenies.
Mú ìrẹ̀wẹsì bá - Èsì ìdánwò wa mú ìrẹ̀wẹ̀sì bá mi
Discourage - Our examination result discouraged me
Pàtẹ - Àwọn ọlọ́jà máa pàtẹ ọjà ni ọ̀sán
Display - The traders will display their goods at noon
Pa - Òjó pá mí ní àárọ̀ yìí
Drench - I got drenched by the rain this morning
Tòògbé - Ò ń tòògbé
Doze - He is dozing
Fà - Kí ni ẹ ń fà?
Drag - What are you dragging
Tú àṣírí - Ó tú àṣírí wọn
Expose - He exposed their secrets
Sẹ́ - Ìyá ma ṣé ògì
Filter - Mother will filter the pap