Nouns Flashcards
1
Q
Police
A
ọlọpa
2
Q
week
A
ọ̀sẹ̀
3
Q
sunday
A
Ọjọ́ Àìkú - day of not dying
4
Q
monday
A
Ọjọ́ Ajé - day of profit
5
Q
tuesday
A
Ọjọ́ Ìṣẹ́gun - Day of victory
6
Q
wednesday
A
Ọjọ́rú – Day of confusion or day of sacrificing
7
Q
thursday
A
Ọjọ́bọ̀ - Day of coming or day of recent creation
8
Q
friday
A
Ọjọ́ Ẹtì –- Day of failure
9
Q
saturday
A
Ọjọ́ Àbá Mẹ́ta – Day of three suggestions
10
Q
Song
A
Orin
11
Q
School
A
ile ẹkọ
12
Q
Month
A
oṣù
13
Q
Year
A
ọdun
14
Q
Pass
A
kọja
15
Q
Music
A
orin
16
Q
Group
A
agbo
17
Q
Thought
A
èrò
18
Q
Rest
A
ìsinmi
19
Q
Lesson
A
ẹkọ
20
Q
Yesterday
A
ana
21
Q
Today
A
oni
22
Q
money
A
owo
23
Q
mother
A
iya
24
Q
food
A
ounjẹ
25
family
ẹbi
26
parents
obi
27
work
ibi ise/ ile ise
28
chair
aga
29
illness
aisan (aisan corona)
30
Opportunity
aye
31
again/ repitition
tún
32
hope
ireti
33
death
iku (i in front of the verb makes it a noun)
34
cow
maalu
35
dog
aja
36
fish
eja
37
goat
eran
38
chicken
adiye
39
flies
eṣinṣi
40
mosquito
efon
41
cat
ologbo
42
bird
eye
43
cockroach
Ayan
44
egg
Ẹyin
45
teeth
Ẹyín
46
breakfast
ounje aaro
47
lunch
ounje osan
48
dinner
ounje ale
49
Maths
Isiro
50
disease
uku-uku
51
mosquito
yanmu-yanmu
52
early morning
aaro kutukutu
53
day before yesterday
ijeta
54
day after tomorrow
otunla
55
last week
ose to koja
56
next week
ose to nbo
57
what happened the day before yesterday?
ki lo se le ni ijeta?
58
father's day
ojo ayeye baba
59
speak for people to understand
aláwìíyé
60
gym
idaraya
61
church
ile-ijosin
62
shop
ate
63
time
asiko/akoko
64
words
ọrọ
65
problem
ìṣòro
66
best friend
ore mi atata/ ore mi gidi/ ore mi ti mo ti mo
67
worker
Oṣiṣẹ
68
hairdresser
onidiri
69
hour
Wákàtí
70
cassava
gbaguda
71
tree
igi
72
soldier
warrior
73
lion
kiniun
74
turning stick
orogun
75
knife
obe
76
sandal
salubata
77
spoon
sibi