Connecting Words Flashcards
Inside
nínú
Each
kọọkan
Like/as
bí
Maybe
boya
After/ Then
lẹyìn
A small
kekere kan
When?
nígbà tí?
All
Gbogbo
Is/are
wà ní
Initially / firstly
Akọkọ
Just
ṣeṣe
Before/ in front of
níwájú
at hand/at present
l’owo
now
nisiyi
with
pelu
without
laisi
far from
jina si
near
nitosi
outside
ita/nita
and
ati
above
loke
downstairs/ under
nisale (wa nisale)/ labe
me too
ati emi na
speak about
so ni pa
for example
bi apeere
at present
l’owo
next week
ni ose to n bo
before (before you go)
ki n tó (Ki ẹ̀ tó lọ )
after/ behind
Lẹhin
in front of
Níwájú
ahead of
Ṣaaju/ Ṣiwaju/
far from
Jìnà sí
near
Nítòsí
in
Inú
inside
Nínú
outside
ita
with
Pẹlu
without
laisi
about
Nípa
between
Láárin
but
Ṣugbọn
for
Fún
from
Láti
to
Sí
helping hand
Iranlọwọ
later
tobaya
always
nigbogbo gba
after that
lehin na
that is
Ti ó ti
I’m looking for my keys that is lost
Mo n wa kọkọrọ mi ti ó ti sọ nù
must
gbọdọ
while
nigbati
unless
afi
no
oti
nothing
kosi
not yet
koiya
since
lati igba
as
bi
instead of
dipo
to
si
of
ti
until
titi di
no longer
ko si mọ
im no longer hungry
ebi ko pa mi mọ
no one
ko si enikan
thing
nkan
when you are going…
ti o ba ti nlo si….
or
abi
cannot
ko le ṣe
usually
leralera
or else
aijẹ bẹ
themselves
ara won
tako
against
to face problem
o do ju kọ wahala/ìṣòro