Greetings Flashcards
E Kaaro (eh-ka-ror)
Morning Greetings
E Kasan (eh-ka-sawn)
Afternoon Greetings
E Kurole (eh-koo-ror-leh)
Dusk/Evening Greetings
E Kaale (eh-kah-leh)
Night Greetings
E Ku jo meta
long time no see
Response “ojo kan pelu”
E Kaabo
= Welcome
Response = E Ku ile = Greetings in the House
Se alaafia ni? (shay ah-laa-feeyah-nee)
Se alaafia lewa?
Are you Well/at Peace? (young person)
Are you Well/at Peace? (older person)
Response: Alaafia ni (ah-laa-fee-yah-nee)
Se daada ni?
Is it good/well? (daada = good)
Response: Daada ni
A dupe
We give thanks
ile iwe rẹ nkọ?
How is your school?
Response: (o wa)
awọn ara ile yin nkọ?
how is everyone at home?
response: (wọn wa)
awọn ọmọ nkọ?
how are your children?
response: (wọn wa)
iṣẹ rẹ/yin nkọ?
How is your work?
Response: (o wa)
awọn ẹbi rẹ nkọ?
how are your family?
response: (wọn wa)
ko buro
no problem