Lesson 3 Flashcards
1
Q
Morning
A
àárò̩
2
Q
Afternoon
A
ò̩sán
3
Q
Evening
A
alé̩
4
Q
Dusk
A
às̩álé̩
5
Q
Nightfall
A
ìrò̩lé
6
Q
Doctor
A
dókítà
7
Q
Nurse
A
nó̩ò̩sì
8
Q
Good Health
A
àláfià
9
Q
Love
A
ìfé̩
10
Q
Happiness
A
inú-dídùn
ìdùn-nú
11
Q
Subject
A
só̩bújé̩è̩tì
às̩àyàn-è̩kó̩
12
Q
Teach (someone)
A
kó̩ (èníyàn)
13
Q
Teach
A
tiìs̩ì
14
Q
Learn
A
ké̩kó̩
15
Q
Teacher
A
tís̩à
olùko̩ni
16
Q
Economics
A
eko̩nó̩miìkìsì
è̩kó̩ ètò-o̩rò̩
17
Q
Geometry
A
jó̩mè̩tìrì
è̩kó̩ ilè̩-wíwò̩n
18
Q
Biology
A
bàó̩kó̩jì
è̩kó̩ è̩dá-oníyè
19
Q
Physics
A
fisíìkísì
è̩kó̩ è̩dá
20
Q
Algebra
A
o̩ligibìrà
è̩kó̩ ìs̩ir`-alàmì
21
Q
English
A
Íngílìís̩ì
22
Q
Mathematics
A
ìs̩irò
23
Q
Geography
A
jó̩firáfì
è̩kó̩ ilè̩ ayé
24
Q
History
A
ístìrì
è̩kó̩ ìtàn-àko̩ó̩lè̩
25
Religious Studies
ò̩kó nípa ìgbàgbó̩
26
Chemistry
ké̩místìrì
| è̩kó-è̩là
27
Religion
rìlíjìò̩nù
28
Where do you come from?
Ibo l'o ti wá?
29
Where is your town?
Ibo ni ìlú re̩?
30
I come from Houston
Houston ni mo ti wá
31
Sugarland is my town
Sugarland ni lú mi
32
Where is your village?
Ibo ni abúlé yin?
33
Harris County is my village
Harris county ni abúle wa
34
Where is your school?
Ibo n'ilé-ìwé re̩ wà?
35
My school is in Montrose
Montrose ni ilé-ìwé mí wà
36
Where do you go to school?
Ibo l´o ti nlo̩ sí skùúlù?
37
Which college (university) do you attend?
Ilè è̩kó̩ gíga (Yunifásítì) wo l'ò nlo̩?
38
Where is your school?
Ibo ni ilé-ìwé re̩?
39
I attend school in Montrose
Mo nlo̩ skúúlù ní Montrose
40
I attend the University of St. Thomas
Mo nlo̩ Yunifásítìi ti St. Thomas
41
I attend a teacher's college
Ilé è̩kó̩ gíga ti olùkó̩ni àgbá ni mò nlo̩
42
I attend a technical school
Iké-èkó̩ gíga ti awo̩n as̩è̩ro̩ ni mò nlo̩
43
I go to Yaba College of Technology
Ilé-è̩kó̩ as̩è̩ro̩ ti Yaba ni mò nlo̩
44
What do you study?
Irúè̩kó̩ wo l'ò nkó̩?
45
I study education.
Mo nkó̩ is̩é akó̩ni
46
What is your major?
Kíni májò̩ re̩?
47
I major in nursing
Is̩é̩ nó̩ò̩si ni mo ti méjò̩