Lesson 2 Flashcards
Vocabulary and Expressions
Dog
ajá
Mouth
Ẹnu
Ear
Etí
Head
Orí
Eye
Ojú
Friend
Ọ̀rẹ́
Money
Owó
Business
Òwò
To see
Láti rí
To sleep
Láti sùn
To like, to love
Láti fẹ́ràn
To love
Láti fẹ́
To eat
Láti jẹ
To go
Láti lọ
To come
Láti wá
To have
Láti ní
To come back
Láti bó̩
Given name
Orúko̩ abíso̩
Baptismal name
Orúko̩ ìdílé
Surname
Orúko̩ ìdílé
House
ilé
Farm
oko
New York
Níú Yo̩ò̩kì
Chicago
S̩ikágò
Los Angeles
Lo̩s Ánjé̩líísì
Dallas
Dáláàsì
Manager
máníjà
Doctor
dókítà
Doctor
onís̩ègùn
Lawyer
ló̩yà
Lawyer
abge̩jó̩rò
Engineer
e̩njiníà
Businessman
onìs̩òwò
Craftsman
onís̩é̩-o̩wó̩
What is your name?
Kínì orúko̩ re̩?
My name is ______
Orúko̩ mi ni ______
The name that I’m called
Orúko̩ tí à npè mí nì ______
My natural name (name given by circumstances of birth) is
Orúko̩ àmútò̩runwá mi ni _____
My baptismal name is Joseph
Orúko̩ ìsàmi mi ni _____
My nickname is
Orúko̩ ìnagijo̩ mi ni _____
People call me Adisababa
Wó̩n npè mi ni _____
What is your father’s name?
Kini orúko̩ bàbà re̩?
My father’s name is
Orúko̩ bàbá mi ni _____
My wife’s name is
Orúko̩ ìyàwó mi ni _____
My son’s name is
Orúko̩ o̩mo̩ mi ni _____
Where do you live?
Ibo ni ò ngbé?
I live in
Mò ngbéní _____
What is your gender?
Kini ìrin re̩?
I am male
O̩kùnrin l’èmi
I am female
Obìnrin l’emi
What kind of work do you do?
Irú is̩e̩ wo l’ò ns̩e?
I am a bricklayer
Mò ns̩e isé̩ bíríkìlà
I am a carpenter
Mò ns̩e isé̩ káfé̩ntà