Lesson 1 Flashcards
Greetings
1
Q
How are you/How’s everything?
A
Bawo ni nkan?
2
Q
Good night
A
O d’àáarọ̀
3
Q
How are you?
A
Bàwo ni?
4
Q
Hello there
A
Pẹ̀lẹ̀ o
5
Q
Goodbye
A
Ó dàbọ̀
6
Q
Be careful
A
Ẹ rọra
7
Q
Watch your step
A
Ẹ máa wolẹ́
8
Q
How are you?
A
Ṣé àláfíà ni?
9
Q
Good morning
A
Ẹ káàrọ̀
10
Q
Good afternoon
A
Ẹ káàsán
11
Q
Good evening
A
Ẹ kúrọ̀lẹ́
12
Q
Good night
A
Ẹ káalẹ́
13
Q
Greetings for the celebration
A
Ẹ kú ọdún
14
Q
Happiness
A
ayọ̀
15
Q
Father
A
Bàbá
16
Q
Mother
A
Ìyá
17
Q
Wealth
A
ọlá
18
Q
God
A
Ọlọ́run
19
Q
Child
A
ọmọ
20
Q
Gratitude
A
ọpẹ́
21
Q
Money
A
owó
22
Q
Title
A
oyè
23
Q
To give birth
A
Láti bí
24
Q
To come back
A
Láti dé
25
To give
Láti fún
26
To awake
Láti jí
27
To cry
Láti ké
28
To Have, To Say
Láti ní
29
To go
Láti lọ
30
To see
Láti rí
31
To eat
Láti jẹ
32
To come
Láti wá
33
Professor
Pròfẹ́sọ̀
| Ọ̀jọ̀gbọ́n
34
Teacher
Tíṣà
| Olùkọ́
35
Senior Teacher
olùkọ́-àgbà
36
Schoolchild
ọmọ ilé-ìwé
37
Student
akẹ́kọ
38
University
Yunifásítì
39
Any school beyond high school
ilé-ẹ̀kọ́ gíga
40
Yoruba Language
èdè Yorùbá
41
Ibo Language
èdè Íbò
42
Hausa Language
èdè Haúsá
43
English Language
èdè Lárúbáwá
44
Ibo Language
èdè Òyìnbó
45
Yoruba Language
èdè Káarọ̀-o-òjíire
46
Friend
Ọ̀rẹ́
47
Father
Baba
48
Mother
Ìyá
49
Dog
Ajá
50
Town
Ìlú
51
School
Skúúlù
52
School
Ilé-ìwé
53
Teacher
Tíṣà
54
Teacher
Olùkọ́
55
Parent
Òbí
56
To be big
Lati tóbi
57
To be beautiful
Lati dára
58
To be far
Lati jìnná
59
I
Èmi
60
I am
Èmi ni
61
We
Àwa
62
We are
Àwa ni
63
You
Ìwọ
64
You are
Ìwọ ni
65
My name is
Orúkọ mi ni _____
66
My friend's name is
Orúkọ ọ̀rẹ́ mi ni _________
67
My dog's name is
Orúkọ ajá mi ni _______
68
My town's name is
Orúkọ ìlú mi ni _______
69
My school is big
Skúùlù wa tóbi
70
My school is far
Skúùlù mi jìnnà
71
I am your (plural) friend
Èmi ni ọ̀rẹ́ yín
72
I am your (singular) friend
Èmi ni baba rẹ
73
I am Ade's mother
Èmi ni Ìyá Ádé
74
We are Bola's friend
Àwa ni ọ́rẹ́ Bola
75
You are Akin's friend
Ìwọ ni ọ̀rẹ́ Akin
76
We are Ayo's parents
Àwa ni òbí Ayọ́