Adjectives Flashcards
Olówó - Olówó ni bàbá mi
Rich - My father is a rich man
Akúùṣẹ́ - Akúùṣẹ́ ni ọkùnrin yẹn
Poor - That man is a poor man
Onírẹ̀lẹ̀ - Ónírẹ̀lẹ̀ ènìyàn ní Adé
Humble - Ade is a humbleperson
Onígbèrága - Onígbèrága ni wọ́n
Proud - He is a proud person
Alágbára - Alágbára ni wọ́n
Strong - He is a strong person
Ọlọyàyà - Ọláyàyà ni ìyá mi
Cheerful - My mother is a cheerful person
Ọlọ́gbọ́n - Ọlọ́gbọ́n ni wọ́n
Wise - He is a wise person
Olókìkí - Olókìkí ni Ṣọlá
Popular - Sola is a popular person
Gíga - Ènìyàn gíga ni
Tall - He is tall/He is a tall person
Kúkúru - Ṣọlá kúkurú
Short - The short Sola
Títóbi - Ènìyàn títóbí ni wọ́n
Big - He is a big person
Ògbójú - Ògbójú ènìyàn ni
Bold - He is a bold person
Fífẹ̀ - fún mi ní abọ́ fífẹ̀
Broad - Give me the broad plate
Lílé - Ènìyàn lílé ni Ọlá
Tough - Ola is a tough person
Dáradára - Ọmọ dáradára ni ẹ (dáadáa/Dada)
Good - You are a good child
Púpọ̀ - Mo rí àwọn ènìyàn púpọ̀ nílé wọn
Plenty - I saw plenty of people in her house
Dúdú - Ènìyàn dúdú ni
Dark - She is dark in complexion
Pupa - Ènìyàn pupa ni màmá mi
Fair - My mother is a fair person
Funfun - Nǹkan funfun ni
White - It is white
Wúwo - Ó wúwo
Heavy - It is heavy
Ojo - Ojo ni wọ́n
Coward - He is a coward
Ọ̀lẹ - Ọ̀lẹ ni
Lazy - He is lazy
Burúkú - Máà jẹ́ ènìyàn burúkú
Bad - Do not be a bad person
Òmùgọ̀ - Má ya òmùgọ̀
Fool - Do not be a fool