Adjectival verbs Flashcards
Nírẹ̀lẹ̀ - Wọn ò nírẹ̀lẹ̀
Humble - He is not humble
Gbéraga - Ó ń gbéraga
Proud - He is proud
Lágbára - Wọn ò lágbára
Strong/powerful - They are not strong
Lọ́yàyà - Wọ́n lọ́yàyà
Cheerful - She is cheerful
Lọ́gbọ́n - Ó lọ́gbọ́n
Wise - She is wise
Lókìkí - Wọn ò lókìkí
Popular - She is not popular
Lágídí - Mi ò lágídí
Stubborn - I am not stubborn
Ga - Tunde ga gan-an
Tall - Tunde is very tall
Kúrú - Ó kúrú
Short - She is short
Tóbi - Ilée wọn tóbí
Big - her house is big
Fẹ̀ - Ọ̀nà yẹn ò fẹ̀
Broad - The road is not broad
Sanra - Mi ò fẹ́ sanra
Fat - I do not want to be fat
Dára - Ọmọ yẹn dára
Good - That child is good
Le - Mi ò le
Tough - I am not tough
Pọ̀ - Ó pọ̀
Plenty - It’s plenty
Dúdú - Wọn ò dúdú
Dark - She is not dark in complexion
Pupa - Mi o pupa
Fair - I am not fair in complexion
Funfun - Aṣọ ẹ̀ ò funfun
White - His cloth is not white
Wúwo - Kò wúwo
Heavy - It is not heavy
Kúṣẹ̀ẹ́ - Wọn ò kúṣẹ̀ẹ́
Poor - He is not poor
Lówó - Ṣé o lówó?
Rich - Are you rich
Tínínrín - Ó tínínrín
Thin - It is thin
Gbóná - Tíì mi gbóná gan-an
Hot - My tea is hot
Tutù - Omi ti tutù
Cold - The water is cold