Yoruba - Command Tone Flashcards
1
Q
Talk! / Don’t talk! (Honorific)
A
Ẹ sọ̀rọ̀! / Ẹ má sọ̀rọ̀! (Honorific)
2
Q
Eat! / Don’t Eat (Casual)
A
Jẹun! / Má jẹun! (Casual)
3
Q
Come eat! / Don’t come eat! (Honorific)
A
Ẹ wá jẹun! / Ẹ má wá jẹun!
4
Q
Go to sleep! (Honorific)
A
Ẹ lọ sùn!
5
Q
Don’t go to sleep! (Honorific)
A
Ẹ má lọ sùn!
6
Q
Get out! / Don’t go out! (Honorific)
A
Ẹ jáde! / Ẹ má jáde!
7
Q
Enter!/Go in!/Come in! / Don’t enter! (Honorific)
A
Ẹ wọlé! / Ẹ má wọlé!