Vocab Flashcards
1
Q
Káàárọ̀
A
Good morning
2
Q
Káàsán
A
Good afternoon
3
Q
Kúùrọ̀lẹ́
A
Good evening
4
Q
Káalẹ́
A
Good (late) evening
5
Q
ó dàárọ̀
A
Good night
6
Q
Báwo ni?
A
How are you?
7
Q
Dáadáa ni.
A
Fine.
8
Q
Túnjí wà ń’lé.
A
Tunji is/was home.
9
Q
Túnjí kò sí ń’lé.
A
Tunji is/was not home.
10
Q
ọ̀rẹ́
A
friend
11
Q
kò burú
A
it’s not bad / it’s OK
12
Q
padà wá
A
to return
13
Q
ó dàbọ̀
A
goodbye
14
Q
ẹ ṣé
A
thank you (hon.)
15
Q
kò tọ́pẹ́
A
don’t mention it / you’re welcome
16
Q
wà
A
to be in a place
17
Q
rárá
A
no
18
Q
O lọ sọ́jà.
A
You went to the market.
19
Q
Ṣé o lọ sọ́jà?
A
Did you go to the market?
20
Q
Bẹ́ẹ̀ ni, mo lọ sọ́jà.
A
Yes, I went to the market.
21
Q
Rárá, N kò lọ sọ́jà.
A
No, I didn’t go to the market.
22
Q
Mo lọ sílé Adé.
A
I went to Ade’s house.
23
Q
Kúnlé rí i.
A
Kunle saw him.
24
Q
Mo rìn.
A
I walked.
25
Olú ní bàtà.
Olu has/had shoes.
26
Ó dára.
It is/was good.
27
Mo wà nílé.
I am/was home.
28
Túnjí wà ń’lé.
Tunji is/was home
29
Túnjí kò sí ń’lé.
Tunji is/was not home.
30
Kúnlé máa padà wá.
Kunle will return.
31
Kúnlé kò ní í padà wá.
Kunle will not return.
32
ẹ̀gbọ́n
older sibling
33
dà?
where?
34
kò ì tí ì
has not ...
35
dé
to come back
36
lọ́la
tomorrow
37
ó dàárọ̀
good night
38
Ẹ̀gbọ́n ẹ dà?
Where is your older sibling?
39
Níbo ni ẹ̀gbọ́n ẹ wà?
Where is your older sibling located?
40
Mo ti jẹun.
I had/have eaten.
41
Túnjí wá sí ọjà
Tunji came to market.
42
Kúnlé lọ sí ṣọ́ọ̀ṣì
Kunle went to church
43
Mo lọ sí ilé
I went home
44
N kò sí ní ilé
I was not at home.
45
àbúrò
younger sibling
46
mùsíọ̀mù
museum
47
ilé-ìwé
school
48
ọ́fíìsì
office
49
ilé-ìkàwé
library
50
ilé-ọkọ̀ òfurufú
airport
51
ilé-ọkọ̀ ojú-irin
train depot
52
ilé àwọn ẹranko
zoo
53
pẹ̀lẹ́
greetings
54
jí
to wake up
55
dúpẹ́
thank G-d
56
ni
to be
57
jẹun
to eat
58
kò/ò
negative marker
59
ò níí
will not
60
Sà
sir
61
ti
perfective (have/has)
62
ṣẹ̀ṣẹ̀
just recently
63
pẹ́
to be late
64
ń lọ
is going
65
síbi iṣẹ́
to a place of work
66
Èmi
emphatic I