Basic Phrases/Useful Words Flashcards
1
Q
Ẹ káàárọ̀
A
Good Morning
2
Q
Ẹ káàsán
A
Good Afternoon
3
Q
Ẹ káalẹ́
A
Good Evening/Night
4
Q
Ṣé dáadáa ni?
A
How are you? (informal)
5
Q
Báwo ni?
A
How are you? (informal)
6
Q
Ṣé àlàáfíà lẹ wà?
A
How are you? (formal)
7
Q
àlàáfíà ni
A
I’m fine (formal)
8
Q
dáadáa ni
A
I’m fine (informal)
9
Q
Adúpẹ́
A
I’m fine (informal)
10
Q
Orúkọ mi ni
A
My name is
11
Q
Kí l’orúkọ ẹ?
A
What is your name?
12
Q
Ẹ Jọ̀ọ́
A
Please
13
Q
Ẹ má bínú
A
Sorry
14
Q
Ẹ ṣé
A
Thank you
15
Q
Bẹ́ẹ̀ ni
A
Yes