At A Friend’s House Flashcards
1
Q
Good evening
A
Kúùrọ̀lẹ́
2
Q
How are
A
Báwo ni
3
Q
To not be
A
Kò sí
4
Q
To go
A
Lọ
5
Q
At a place
A
sọ́dọ̀
6
Q
Things
A
nǹkan
7
Q
Fine
A
dáadá ni
8
Q
Please
A
jọ̀ọ́
9
Q
How is/where is …?
A
…ńkọ́?
10
Q
At home
A
ń’lé
11
Q
Friend
A
Ọ̀rẹ́
12
Q
It’s ok
A
kò burú
13
Q
Return
A
padà wá
14
Q
Goodbye
A
ó dàbọ̀
15
Q
You’re welcome
A
kò tọ́pẹ́
16
Q
Is Tunji home?
A
Ṣé Túnjí wà ń’lé?
17
Q
Did you got to the market?
A
Ṣẹ́ o lọ sọ́jà?
18
Q
Is Dele Tunji’s friend?
A
Ṣé Délé ni ọ̀rẹ́ Túnjí?
19
Q
Yes, Tunji is home
A
Bẹ́ẹ̀ ni, Tunjí wà ń’lé
20
Q
No, Tunji is npt home
A
Rárá, Túnjí kọ̀ sí n’lé
21
Q
Yes, I went to the market
A
Bẹ́ẹ̀ ni, mo lọ sọ́jà
22
Q
No, I did not go to the market
A
Rárá, N kọ̀ lọ sọ́jà